YORUBA COUNCIL OF YOUTH WORLDWIDE (YCYW) KI BABA RERE, DISTINGUISHED HON IBRAHIM AYOKUNLE ISIAKA (MHR IFO/EWEKORO ), AARE ASOJU OODUA LAGBAYE, ASOLUDERO OF EGBALAND,KU ORIIRE ỌJỌ IBI


Ni Orúkọ Gbogbo Igbimọ Ọdọ Yorùbá Lágbayé ẹka tí Ipinlẹ Ogun labẹ Àṣẹ Alaga wa AsojuOdo Omoluabi Sunday Adebowale a ki baba wa, baba rere, Distinguished Hon IBRAHIM ISIAKA, (MHR Ifo/Ewekoro Federal constituency) ku ayẹyẹ ọjọ ìbí wọn loni ọjọ kefa (6), Oṣu keje (July), ọdún 2023

A si gba ni adura npe ki ọlọrun tún bọ máa b'awa lọra ẹmi yin ninu ọlá, ninu ipo, ninu ọgbọn àti oye ti ẹ fi tunbọ máa ṣe ìlú ifo/Ewekoro lọ síwájú si, paapa julọ ninu àìkú baálẹ̀ ọrọ.

Lẹẹkansi ẹku oriire ọjọ ibi, ẹmi yin aṣe púpọ ọdún láyé, lágbára ọlọrun àti àwọn tó tẹ ilẹ yorùbá dó. Àṣẹ!

A si tun fi akoko yi dupẹ lọwọ yin Lẹẹkansi fún ipa ribiribi ti ẹtì nko l'agbo òṣèlú ati ìdàgbàsókè ,ifo/Ewekoro, ipinlẹ Ogun, paapa julọ ni ẹka ti idagbasoke ati ofin sise Nile igbimo asofu agba l'abuja fun gbogbo orilẹ-ède Naijiria lapapọ, ẹ ṣe gan adupẹ, ki ọlọrun bawa kun yin lọwọ.

Ọmọ Yorùbá ni mí, Ọmọ kaarọ ojiire!

Fún igbimọ ọdọ ipinlẹ ogun,

E-signed:

AsojuOdo Omoluabi Sunday Adebowale
Chairman, YCYW Ogun State Council

Through:

Omoluabi Yusuf Wasiu Olamilekan
(Oko Momi)
Media and Publicity Secretary, YCYW, Ogun State
Ycywogunstate@gmail.com
6/7/2023

Comments

Popular posts from this blog

CELEBRATING THE EXTRAORDINARY LEADERSHIP OF AARE OLANREWAJU MICHAEL GEORGE (OMG) -Olumide Adebayo (McAnelka)

HON. OGUNLEYE COMMISSIONS LANDMARK PROJECTS IN IKENNE LOCAL GOVERNMENT

IKENNE LOCAL GOVERNMENT BOSS CONGRATULATE ALHAJI APELOGUN ON HIS RE-ELECTION